Jump to content

Jolly Nyame

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Jolly Nyame (à pè já -Jolly Tavoro Nyame) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria, láti ìjọba ìbílẹ̀ Zing, ní Ìpínlẹ̀ Tàràbà. A bi ni ọjọ́ kẹẹdọgbọn, oṣù Kejìlá ọdún 1955. Ó ti fi ìgbà kan jẹ́ gomina Ipinle Taraba (ọjọ́ kọkàn-dín-lọ́gbọ̀n, oṣù karùn, ọdún 1999 títí di ọjọ́ kọkàn-dín-lọ́gbọ̀n, oṣù karùn, ọdún 2007).

Àwọn itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]