Umuahia

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Umuahia

Umuhu-na-Okaiuga

Umuahia Ibeku
Orile-ede Nàìjíríà
Ìpínlẹ̀Ábíá
LGAÀríwá Umuahia, Gúúsù Umuahia
Population
 • Total359,230
Time zoneUTC+1 (WAT)
Postcode
440...
Area code(s)088

Umuahia ni ìlú tí ó jẹ́ Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Abia ní gúúsù ìlà oòrùn orílè-èdè Nàìjíríà.[2][3][4] Umuahia wà lọ́nà oju irin tí ó wà láàrin Port Harcourt àti ìlú Enugu. Àwọn ẹ̀yà igbo ni ó wọ́pọ̀ ní Umuahia. Umuahia ní olùgbé 359,230 gẹ́gẹ́ bí àbáyọ rí ounka ènìyàn ọdún 2006 ní Nàìjíríà ṣe fi léde. Àwọn ẹ̀yà igbo ni ó wọ́pọ̀ ní Umuahia. Umuahia ní Agbègbè Ijoba Ìbílẹ̀ méjì: Umuahia North àti Umuahia South.

Àwọn Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]