Ìpínlẹ̀ Ábíá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Ìpínlẹ̀ Ábíá
Abia tower.jpg
Nickname(s): 
God's Own State / Ulo Chi/Chukwu in Igbo Language.
Ibudo ni Naijiria
Ibudo ni Naijiria
Orile-ede Nigeria
OluiluUmuahia
Ijoba Ibile17
Idasile27 August 1991
Government
 • GominaOkezie Ikpeazu(People Democratic party)
 • Awon AlagbaEyinnaya Abaribe, Uche Chukwumerije, Nkechi Justina Nwaogu
 • Awon aranise Ile-igbimo AsofinAkojo
Area
 • Total6,320 km2 (2,440 sq mi)
Population
 (2006 ikaniyan)[1]
 • Total2,833,999
Time zoneUTC+0 (GMT)
GeocodeNG-AB
GIO (2007)$18.69 billion[2]
GIO ti Enikookan$3,003[2]
Ede ibiseIgbo
Geesi
Websitewww.abiastateonline.com/

Ìpínlẹ̀ Ábíá je ikan ninu awon ipinle 36 ni orile-ede Naijiria. Umuahia ni oluilu re wa bo ti le je pe Abá ni ilu gbangba fun aje. Ni odun 1991 ni ijoba Babangida da sile lati apa Ipinle Imo. Awon aralu to po ni be je Igbo (95% awon onibugbe).[3]

Àwọn Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ (17):

Awon eeyan pàtàkì[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]