Jump to content

Dutse

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Dutse
Àwòrán ìgboro ní ìlú Dutse
Orílẹ̀-èdè Nigeria
IpinleIpinle Jigawa

Dutse ni olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Jigawa ní Ariwa Nàìjíríà. Ibẹ̀ ni Yunifásitì ìlú Dutse tí wón dá kalẹ̀ ní oṣù kọkànlá ọdún 2011kalẹ̀ sí. Àwọn olùgbé Dutse jẹ́ 153,000,[1] òun sì ni ìlú tí ó tóbi jù ní ìpínlẹ̀ Jigawa.


Àwọn Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Dutse". World Gazetteer. Stefan Helders. Archived from the original on 2013-02-10. Retrieved 2007-02-18.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)