Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ona Ara

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Ona Ara)

Agbegbe Ijoba Ibile Ona Ara je agbegbe ijoba ibile ni Ipinle Oyo. Akanran ni oluilu re.

Alaga to di ibo wole gegebi alakoso nibe ni Ogbeni Biliaminu Ogundele. Ohun ni ogba ipo lowo araare gegebi alaga-fidihe, eyiti gomina ipinle Oyo yen lati mule lowo ki ibo too de ni ibere odun 2018 yi. Eni toti wa nibe tele gegebi alaga-fidihe ni Ogbeni Sina Adeagbo.

Awon abule:



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]