Ìjọba ìbílẹ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Àdàkọ:Original research

Ìjọba ìbílẹ̀ jẹ́ ìṣèjọba tí ó kéré jùlọ, tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ìpín ágbègbè kọ̀ọ̀kan láti jẹ́ kí ètò ìṣèjọba pẹ́ẹ́pẹ̀ẹ̀pẹ́ẹ́ sún mọ́ àwọn ará ìlú. [1] Ó jẹ́ ìpín ìṣèjọba tó kéré sí Ìjọba Ìpínlẹ̀ àti ìjọba Àpapọ̀, pàápàá pàápàá jùlọ lorílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [2] Lábẹ́ ètò ìṣèjọba Àpapọ̀ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Ìjọba Ìbílẹ̀ máa ń wà lábẹ́ àkóso yálà ìjọba Ìpínlẹ̀ tàbí Ìjọba Àpapọ̀.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Definition of LOCAL GOVERNMENT". Definition of Local Government by Merriam-Webster. 2020-01-29. Retrieved 2020-02-10. 
  2. Level, Education (2014-06-04). "What Is Local Government? - Definition, Responsibilities & Challenges - Video & Lesson Transcript". Study.com. Retrieved 2020-02-10.