Òṣèlú

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Democracy)

Òṣèlú je ijoba ìṣèlú ará ìlu boya to ba wa taara lati owo awon ara ilu tabi ki won fun awon asoju won lase ninu idiboyan lati lo agbara yi. Àwon elédè Gèésì n pèé ní democracy to wa lati inú ede Griiki: δημοκρατία - (dēmokratía) tí ó tumo si "agbara aralu"[1] eyi ti won yi wa lati δῆμος (dêmos), "aralu" ati κράτος (krátos) "agbara" larin orundun ikarun-ikerin kJ lati toka si iru ìlànà oselu to wa nigba náà ni awon ilu orile-ede Grisi, pataki ni Ateni Atijo leyin rogbodiyan odun 508 kJ.[2]




Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Demokratia, Henry George Liddell, Robert Scott, "A Greek-English Lexicon", at Perseus". Archived from the original on 2007-09-14. Retrieved 2007-09-14. 
  2. "democracy - History, Development, Systems, Theory, & Challenges". Encyclopedia Britannica. 1992-12-07. Retrieved 2018-11-07.