Oluwaseyi Makinde

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Oluseyi Abiodun Makinde
Fáìlì:001 Seyi Makinde at LSE Africa Summit.jpg
Seyi Makinde ní LSE Africa Summit
Gomina Ipinle Oyo
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
May 29, 2019
AsíwájúAbiola Ajimobi
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Oluseyi Abiodun Makinde

Oṣù Kejìlá 25, 1967 (1967-12-25) (ọmọ ọdún 52)
Ibadan
AráàlúNigerian
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party
(Àwọn) olólùfẹ́Tamunominini Makinde
Àwọn ọmọ3
ÌyáAbigail Makinde
BàbáOlatubosun Makinde
EducationUniversity of Lagos
OccupationPolitician, Engineer
Known forGroup Managing Director of Makon Group Limited

ṣèyí Abiọ́dún Mákindé ni a bí ní ọjọ́ Karùndínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá, ọdún 1967 (25 December 1967). Ó jẹ́ oníṣòwò, olóṣèlú àti ọlọ́rẹ àtinúwá Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni Gómìnà tí ó ń bẹ lórí àléfà lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́[1] ní apá Ìwọ̀-Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà.[2] Wọ́n dìbò yàn-án ní Ọdún 2019 lábé àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party (PDP) Ó jẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ àti onímọ̀ nípa ìwọ̀n epo àti afẹ́fẹ́ gáàsì (fluid and Gas Metering).[3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]