Victor Omololu Olunloyo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Victor Omololu Olunloyo
Gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo
In office
October 1983 – December 1983
AsíwájúBola Ige
Arọ́pòOladayo Popoola
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kẹrin 1935 (1935-04-14) (ọmọ ọdún 89)
Àwọn ọmọKemi Omololu-Olunloyo (ọmọ obìnrin)

Victor Omololu Olunloyo (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹrin ọdún 1935) jẹ́ onímọ̀ Mati tí ó di Gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo, Nàìjíríà ní oṣù Kẹ̀wá ọdún 1983, ó di ipò náà mú fún ìgbà díẹ̀ kí ìjọba ológun Muhammadu Buhari tó gba ìjọba ní oṣù Kejìlá ọdún 1983. Ó padà darapọ̀ ẹgbẹ́ òsèlú People's Democratic Party (PDP) ní Ìpínlẹ̀ Oyo.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]