Jump to content

Saheed Osupa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Saheed Osupa
Orúkọ àbísọSaheed Akorede Babatunde Okunola
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiKing of Fuji, Olufimo, Matagbamole
Ọjọ́ìbí7 Oṣù Kẹjọ 1969 (1969-08-07) (ọmọ ọdún 57)
Ajegunle, Lagos, Lagos State, Nigeria
Ìbẹ̀rẹ̀Ibadan (Ayeye)
Irú orin
Occupation(s)Singer-songwriter
InstrumentsVocals
Years active1983–present
Associated actsOriste Femi,

Saheed Akorede Babatunde Okunola ti a bi ni ojo keje, osu kejo odun 1970, ti a tun mon si Saheed Osupa tabi King Saheed Osupa ( KSO), je osere Fuji ati ere ori itage ni orile-ede Naijiria.

Ìgbésí ayé ara eni

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Saheed osupa jẹ́ ọkùnrin ti o feran ebi, ó sì ní ìdílé ńlá. Ó fẹ́ ìyàwó méjì, tí orúkọ wọn ń jẹ́ Azeezat àti Olabisi muinat, ó sì ní ọmọ mẹ́jọ lápapọ̀ - ọmọkùnrin mefa àti ọmọbìnrin méjì.[1]

Ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Adugbo Mosafejo to wa ni Ajegunle ni ipinle Eko ni won bi Saheed Osupa si sugbon o dagba ni ilu Ibadan ti o je olu ilu ipinle Oyo.[2] Bàbá rẹ̀, Moshood Ajiwere Layeye, jẹ́ olórin orin Wéré àti ìbátan àgbà fún olórin Fuji ti a mon si Ayinde Barrister.[3]

Osupa lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga Amuwo Odofin ní Èkó, ó sì parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ọdún 1987.[4] Ní ọdún 1992, ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí National Diploma ní ile-iwe giga The Polytechnic, Ibadan lẹ́yìn tí ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa Business Administration . Ó jẹ́ ọmọ ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti American International College, níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn iṣẹ́ Networking Operations.[5]

Osupa bẹ̀rẹ̀ orin fuji kiko ni odo gege bi iṣẹ́ ní ọdún 1983. Àwo orin àkọ́kọ́ rẹ̀ ni Fuji Fa Disco, lẹ́yìn náà ni Fuji Blues . Ó ti gbé àwọn àwo orin tó lé ní ogójì jáde, títí kan àwo orin onílé-iṣẹ́ mẹ́rin nínu eyokan tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Mr. Music.[6] Ní ọdún 2008, Ayinde Barrister kéde Osupa gẹ́gẹ́ bí "Ọba Orin Fuji".[7]

Ní ọjọ́ ogún oṣù Kejìlá ọdún 2014, Osupa ṣe àgbékalẹ̀ orin hip hop kan tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ "Vanakula" tí K-Solo ṣe.[8] Ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹrin ọdún 2015, ó ṣe àgbéjáde orin K-Solo mìíràn tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ "African Beauty" pẹ̀lú àwọn ohùn láti ọ̀dọ̀ Yetunde Omobadan.[9] Ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹjọ ọdún 2015, ó ṣe àfihàn Seriki nínú orin mìíràn tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ "Womi".

Ní ọjọ́ keje oṣù kọkànlá ọdún 2015, wọ́n kọ orúkọ Osupa sí ọ̀kan lára àwọn akọrin tó ṣe àṣeyọrí jùlọ ní ' ní NET.[10][11]

Ní ọjọ́ kejìlá oṣù kẹfà ọdún 2018, Osupa gbé àwo orin hip Fuji àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde, ti akole re un je Non-Stop .

Osupa ti farahàn ninu awọn fiimu Yoruba to ju ọgbọ̀n lọ. Díẹ̀ lára àwọn fíìmù tó gbajúmọ̀ tí ó ṣe àfihàn rẹ̀ ni:

  • Alukoro
  • Eni eleni
  • Èsè mífà laye
  • Ero sese koowe
  • Ose maami
  • Irumole Osupa
  • Oludegun Alagbara
  • Ogun Iwase
  • Alakoso Sango
  • Agbere Oju ati be be lo.

Aawo pelu Wasiu Alabi Pasuma

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Osupa ati Wasiu Alabi Pasuma ti ni aawo. Osupa gbe àwọn àwo orin tó tó mewa jáde lórí ìjà wọn. Ija naa tesiwaju titi di ọdun 2012. Osupa sọ pe ọpọlọpọ awọn ipade alaafia ti ko ni eso waye ni ọdun 2010 ati 2011.

Àwọn àwo orin tí a yàn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Gege bi Oga Akorin
Ọdún Àkọlé Àwo orin
2014 "Vanakula" TBA
2015 "Ẹwa Afirika" (Yetunde Omobadan) TBA
"Womi" (Seriki) TBA
2018 "Labodan" (Temitope Kush) TBA
"Abeke" TBA
"Awon Temi" Ft Temitope Kush TBA

Àwọn àwo orin sítídíò

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 

  • Fuji Fadisco
  • Fuji Blues
  • Fuji Demonstration
  • Master Blaster
  • Stainless Fuji
  • Fuji Boggie
  • Unbeatable
  • Shuffle Solo
  • Ovation
  • Scores
  • Hot Shot
  • Advice
  • New Edition (Shuffle Solo 11)
  • Authentic
  • Big Daddy
  • Champion
  • London Delight under Marvin Giwa Promotion
  • African Delight
  • American Fuji Slide
  • World Tour
  • London Extra
  • Respect and Reliable - 2 in 1
  • Fuji Icon
  • Endorsement - 3 in 1
  • Mr. Music - 4 in 1
  • Marriage Affair
  • Barrybration
  • Euro Splash
  • Time Factor
  • Impact
  • Turn By Turn
  • The Main Man
  • Capability
  • Tested and Trusted - 2 in 1
  • Guaranteed
  • Lord of Music - 2 in 1
  • Transparency and Transformation - 2 in 1
  • New Dawn - 2 in 1
  • New resolution
  • Pacesetter 2017
  • Non-Stop 2018
  • Dynamism (13 August 2018)
  • C Caution 2019
  • Integrity (07/08/2019)
  • Permutation (23 December 2019)
  • Special request-2 nd 1 (05/07/2020)
  • Eni Olohun (2020)
  • Permutation(2020)
  • Special Request (2020)
  • What Next (2020)
  • Diary (2021)
  • Direction(2021)
  • Power of Music (2022)
  • Fuji Template (2022)
  • Phenomenon (2023)
  • Everlasting And Oracle (2024)
  • GODSENT (Album, 2024)
  • Oracle (Album, 2024)
  • Everlasting (Album, 2024)
  • Acapella & Metamorphosis (Album, 2026)
  • Eni Eleni
  • Ero Sese Koowe
  • Ese Mefa Laye
  • Ose Maami
  • Ashiru Ejire
  • Onibara Ogunjo
  • Iku Oba
  • Igba Iwase
  • Agbeere Oju
  • Alukoro
  • Àròbá (Àròsọ)
  • Osoro baba ojo
  • Olójú ede
  • Adigun olori odo
  • Onimoto
  • Olokiki Oru 1, 2 & 3

Àwọn ẹ̀bùn àti yíyàn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Ayẹyẹ ẹ̀bùn Ẹ̀bùn Àbájáde
2013 Àwọn Ẹ̀bùn FIBAN Olórin Fuji Tó Dáa Jùlọ A Yaan
Àwọn Ẹ̀bùn Ẹ̀ka Èdè Yorùbá Akọrin Tó Dáa Jùlọ Nínú Iṣẹ́ Òṣèré O gbe igba oroke
2015 Àwọn Ẹ̀bùn Ìdárayá Àwọn Ènìyàn Ìlú AKorin Fuji ti o dara julo O Jawe Olubori
Àmì Ẹ̀bùn Àwọn Aṣeyọrí Nàìjíríà ti Ọdún 2015 Olórin Orin Fuji Tó Dáa Jùlọ A Yaan
2019 Àwọn Ẹ̀bùn Àwòrán Àgbáyé ti Yorùbá Akorin Fuji ti o dara julo O Jawe Olubori

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. ↑ Stets, Regina (2018-08-17). "Saheed Osupa: phenomenal Fuji musician, talented actor and happy father". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2026-07-28.
  2. ↑ Ojoye, Taiwo (2017-04-09). "K1 insulted his master, Barrister". Punch Newspapers. Retrieved 2026-07-28.
  3. ↑ Nation, The (2015-07-17). "I USED TO HAVE STAGE-FRIGHT –SAHEED OSUPA". The Nation Newspaper. Retrieved 2026-07-28.
  4. ↑ "SAHEED OSUPA SPEAKS ON WAR IN THE HOUSE OF FUJI". nigeriafilms.com. 2013-10-25. Archived from the original on 2016-02-05. Retrieved 2026-07-28. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. ↑ "SAHEED OSUPA SPEAKS ON WAR IN THE HOUSE OF FUJI". nigeriafilms.com. 2013-10-25. Archived from the original on 2016-02-05. Retrieved 2026-07-28. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. ↑ Company., Events (2015-12-30). "'My fight with Pasuma is simply over supremacy' -Saheed Osupa". Encomium. Retrieved 2026-07-28.
  7. ↑ "Pasuma Wonder VS Saheed Osupa: Who is taking over Fujidom?". sunnewsonline.com. 2014-08-23. Archived from the original on 2015-11-19. Retrieved 2026-07-28. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. ↑ Alash, Bob (2014-12-23). "New Music: King Saheed Osupa". jaguda.com. Archived from the original on 2016-02-27. Retrieved 2026-07-28. Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. ↑ 新奥2025年免费资料-免费公开资料大全 https://web.archive.org/web/20260728192308/https://www.naijabambam.com/king-saheed-osupa-african-beauty-ft-yetunde-omobadan/. Archived from the original on 2026-07-28. Retrieved 2026-07-28. Missing or empty |title= (help)
  10. ↑ Badmus, Kayode (2015-11-07). "NET SPECIAL: Most successful Nigerian musicians ever". Nigerian Entertainment Today. Retrieved 2026-07-28.
  11. ↑ Only, Appointment (2014-12-19). "Saheed Osupa to drop debut hip hop single, 'VanaKula'". Nigerian Entertainment Today. Retrieved 2026-07-28.