Dibu Ojerinde

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Dibu Ojerinde jẹ́ alábòójútó àgbà fún fún àjọ tón bójútó ètò ìdánwò àṣewọlé ẹ̀kọ́ gíga ní ààrin 10 April 2012 – 1 August 2016. Bẹ̀ẹ́ni alábòójútó àgbà fún àjọ ètò ìdánwò oníwèé mẹ́wàá (Registrar of National Examination Council, NECO) ní ààrin 1999–2007. Bákannáà ẹ̀wẹ̀, ó jẹ́ alábòójútó àgbà fún ìlànà ètò ẹ̀kọ́ (Registrar of National Board for Educational Measurement, NBEM)

Dibu Ojerinde jẹ́ educational administrator and a former Registrar of the Joint Admissions and Matriculation Board, JAMB.[1]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Varsities set irrelevant post-UTME questions and blame candidates for failing – Prof. Dibu Ojerinde, JAMB boss". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2014-12-13.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)