Jump to content

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Ìbàdàn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ibadan North
Market places in Ibadan North
Market places in Ibadan North
Motto(s): 
Pacesetter
Country Nigeria
StateOyo State
Government
 • Local Government Chairman and the Head of the Local Government CouncilSaheed Oladayo Yusuf (PDP)
Time zoneUTC+1 (WAT)

Ibadan North ni Ijoba ibile Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ni Orilede Nàìjíríà. Ilu ilese igakan duro ni Agodi Ibadan. Postal code fun adugbo yen ni 200.[1]

Ìwọ̀n ilẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

O ni agbegbe 27 km2 ati iye 856,988 gege bi ijoba ipinle oyo ti so ni odun 2017.

O de tun ni akeko to daa ati ise eto oro aje pelu Yunifasiti akoko orilede Nigeria, to je Yunifasiti Ibadan, ti wan da ni odun 1948 ati Politekiniki Ibadan ti wan da ni odun 1970 je ki o je ibi alafia.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)