Jump to content

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Atiba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Atiba)
Atiba
Country Nigeria
StateOyo State
Government
 • Local Government Chairman and the Head of the Local Government CouncilKafilat Olakojo (PDP)
Time zoneUTC+1 (WAT)

Atiba jẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Nàìjíríà. Olúùlú rẹ̀ wà ní[1] ìlú Ọffà Mẹ́ta.

Ó ní ìwọ̀n ilẹ̀ tí ó jẹ́ 1,757 km2 àti iye àwọn ènìyàn tí ó jẹ́ 168,246 ní ètò ìkànìyàn 2006. Àmì ọ̀rọ̀ ìfilẹ́tà ìránṣẹ́ àgbègbè náà ni 203.[2]

Àwọn àgbègbè kọ̀ọ̀kan lábẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Àtìbà nìwọ̀nyìí; Agúnpopo, Aremo, Ashipa, Bashorun, Aaatan, Abolupe, Afonja, Agbaa, Agbaakin, Agbaka, Agbalowo-Asa, Agberinde, Ajalaruru, Ajegunle, Ajikobi, Akaparo, Akinku, Alaafin Palace, Alubata, Alusekere, Are-Eromasanyin, Asanminu, Ashamu, Ayetoro, Baago, Balogun Maje, Bangudu, Basorun, Boroboro,  Ekesan, Eleke, Elerinle, Elewi, Gaa Bale Fulani, Gbangba Taylor, Gbanta, Ijawaya, Ikolaba, Ile-Ewe, Ilowagbade, Ilusinmi, Iyalamu, Jowo Ese, Keeto, Koloko, Koso, Lagbondoko Area, Latula, Obagbori, Ode Moje, Ofa-Meta, Ogbegbe, Oke Oloola Area, Oke-Afin Area, Olokun Esin, Olugbile, Ona-Aka, Onireko, Onre Bare, Oota, Oridota, Origbemidele, Orokoroko, Otefon, Saakin, Saamu, Sabo, Sangolokeke, Sarumi, St. Andrews Area.[1]

Orúkọ àwọn aṣojú ìlú ti àtijọ́ àti ti àsìkò yìí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Name Office Tenure
Prince Akeem Adeniyi Adeyemi Local Government Chairman 2007 - 2010
Prince Akeem Adeniyi Adeyemi Caretaker Chairman 2011 - 2014
Okeniyi Gbolagade Caretaker Chairman 2016 - 2018
Hon. Ibrahim Sulaiman Akinkunmi Caretaker Chairman[3] 2020- 2021
Kafilat Olakojo Chairman 2021 - Current

Ìṣẹ̀lẹ̀ ìlú mọ́ọ́ká ní ìjọba ìbílẹ̀ Àtìbà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Ìṣẹ̀lẹ̀ Iná ní Ọjà Akẹ̀sán: Ọjà Akẹ̀sán àtijọ́ , tí a tún mọ̀ sí ọjà ọba, èyí tí ń bẹ láàrin gbùngbùn ìlú náà àti ìrìn mítà díẹ̀ láti ààfin Aláàfin ti ìlú Ọ̀yọ́, Ọba Làmídí Adéyẹmí, èyí tí iná bàjẹ̀ ní òwúrọ̀ ọjọ́ ìsinmi, ọjọ́ karùn-ún oṣù kìíní, ọdún okòọ-ó-lé-lẹ́gbàwá, níbi tí ọ̀pọ̀ ilé ìkẹ́rù pamọ́ sí àti àwọn ọjà olówó iyebíye tí ó tó ogún bílíọ́nù. Àwọn Òlutajà 900 wá nínú ìfòyà àti Ìrora nígbàtí iná ọjà tú àlàáfíà ìlú àtijọ́ náà. Ṣíbẹ̀síbẹ̀, gómìnà tó wà lórí oyè lọ́wọ́ lọ́wọ́, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Seyi Makinde wá sí ìdáǹdè nípa fífi mílíọ̀nù N781.7[4] láti tún ọjà Akẹ̀sán tó ti lé ní Ọdún 400.[5] Ọjà Akẹ̀sán tí wọ́n tún kọ́ di ṣíṣí ní ọṣù kẹfà ọdún 2021.
  • in June 2021.[6]
  • Ìdásílẹ̀ ilé ẹ̀kọ́ gíga Àtìbà. [7]
  • Kíkọ́ ilé iṣẹ́ rédíò Àtìbà tó lọ lọ́wọ́. [8]

Àwọn ìtọ́kasí.

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 "Atiba Local Government Area". www.finelib.com. Retrieved 2022-02-26. 
  2. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 7 October 2009. Retrieved 2009-10-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Principal Officers – Atiba LGA" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-02-26. 
  4. Nigeria, News Agency Of (2020-08-12). "Makinde flags off N781.7m reconstruction of Akesan market in Oyo". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-02-26. 
  5. "How 400-yr-old Oyo market was razed in its first fire incident". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-01-07. Retrieved 2022-02-26. 
  6. "'691 shops, new clinic' -- Oyo unveils rebuilt market 17 months after fire incident". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-06-04. Retrieved 2022-02-26. 
  7. "Home - Atiba University, Oyo, Nigeria". www.atibauniversity.edu.ng. Retrieved 2022-02-26. 
  8. "Approved: N100 Million for Atiba FM + More Updates from Oyo State This Week | Oyo State Feedback Service" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-08-13. Retrieved 2022-02-26. 

Àdàkọ:Coord missing Àdàkọ:LGAs and communities of Oyo State


Àdàkọ:OyoNG-geo-stub