Jump to content

Olaniyi Afonja

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Olaniyi Afonja
Ọjọ́ìbíOlaniyi Mikail Afonja
14 Oṣù Kẹ̀wá 1974 (1974-10-14) (ọmọ ọdún 50)
Oyo State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànSanyeri
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaDurbar Grammar School
Iṣẹ́Oṣere Ori-itage
Ìgbà iṣẹ́1992- till date
Olólùfẹ́Hawawu Omolara Afonja (m. 2013)
Àwọn ọmọ2
AwardsYoruba Movie Academy awards Best Comedy Actor (Nominated) , 2015 City People Entertainment awards Best Movie Producer of the year and Comic Actor of the year

Olaniyi Mikail Afonja Listen ⓘ (ojoibi 14 October 1974), ti gbogbo eniyan mo si Sanyeri, je omo Naijiria apanilerin, osere ati onise fiimu. [1] [2][3]

Igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Olaniyi ti won bi ni agbegbe Bola ni ilu Oyo ni ipinle Oyo gege bi omo akoko fun awon obi re, Olaniyi ti ko eko re ni ile-iwe Alakobere St Michael Òkè-èbó, ipinle Oyo ati Durbar Grammar School, ilu Oyo, ipinle Oyo nibi to ti parí eko re. [4]

Odun 1992 ni Obere ise osere Olaniyi, leyin to darapo mo àwọn egbe oni tiata ti ore kan se afihan re. Ni odun 1996, Olaniyi lo si ipinle Eko lati tẹsiwaju ninu ise re, o si ti kopa ninu opolopo fiimu Agbelewo Yorùbá. [4] [5][6]

  • Obakeye
  • Awero
  • Edun Ara
  • Jenifa
  • Ọpa Kan
  • Koboko
  • Salako Alagbe
  • Omo Iya Meji
  • Mama Ṣe O dara
  • Osole
  • Sanyeri Oloka
  • Area Boys
  • Ise Awakọ
  • Waheed Kolero
  • Afoju Meta

Igbesi aye ara ẹni

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Omolara Afonja ni Iyawo Olaniyi àfònjá njẹ ti o si bi omo meji pelu fún pẹlú .[1]

Amin ẹyẹ ati yiyan

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Odun Eye ayeye Ẹbun Abajade Ref
Ọdun 2014 Ebun Yoruba Movie Academy Awards style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
Ọdun 2015 2015 City People Entertainment Awards style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé [1]
  • Akojọ ti awọn Yorùbá
  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named nobs