Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ori-Ire

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Ori Ire)
Ori Ire
Country Nigeria
StateOyo State
Government
 • Local Government Chairman and the Head of the Local Government CouncilOlateju Michael Alabi (PDP)
Time zoneUTC+1 (WAT)

Agbègbè Ìjọba Ibilẹ jẹ́ agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ wà ní ìlú ìkòyí.

Ó ní agbègbè 2,116km² àti iye ènìyàn tí ó tó 150,628 ní ètò ìkà ènìyàn tí ó wà yé ni ọdún 2006.

Àmì ọ̀rọ̀ ìfilẹ́tà rán ṣẹ́ agbègbè ní 210. Ó ní ìwọ̀n-ilẹ̀ tó tó 2,116 2.[1]

Ojú ọjọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Iwòn ìgbóná tí ìkòyí-ilé ga púpò, pẹ̀lú oṣù kẹ́ta tí ó mú oru jùlọ, pẹ̀lú ìwọ̀n 91°F.[2][3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on October 7, 2009. Retrieved 2009-10-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Ikoyi-Ile Climate, Weather By Month, Average Temperature (Nigeria) - Weather Spark". weatherspark.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-15. 
  3. "Ori Ire, Oyo, Nigeria - City, Town and Village of the world". en.db-city.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-15. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]