Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ori-Ire
Ìrísí
Ori Ire | |
---|---|
Country | Nigeria |
State | Oyo State |
Government | |
• Local Government Chairman and the Head of the Local Government Council | Olateju Michael Alabi (PDP) |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Agbègbè Ìjọba Ibilẹ jẹ́ agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ wà ní ìlú ìkòyí.
Ó ní agbègbè 2,116km² àti iye ènìyàn tí ó tó 150,628 ní ètò ìkà ènìyàn tí ó wà yé ni ọdún 2006.
Àmì ọ̀rọ̀ ìfilẹ́tà rán ṣẹ́ agbègbè ní 210. Ó ní ìwọ̀n-ilẹ̀ tó tó 2,116 2.[1]
Ojú ọjọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Iwòn ìgbóná tí ìkòyí-ilé ga púpò, pẹ̀lú oṣù kẹ́ta tí ó mú oru jùlọ, pẹ̀lú ìwọ̀n 91°F.[2][3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on October 7, 2009. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Ikoyi-Ile Climate, Weather By Month, Average Temperature (Nigeria) - Weather Spark". weatherspark.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-15.
- ↑ "Ori Ire, Oyo, Nigeria - City, Town and Village of the world". en.db-city.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-15.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
Àwọn ẹ̀ka:
- Pages with citations using unsupported parameters
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)
- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from November 2023
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links
- Àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́