Samuel Ajayi Crowther

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Samuel Adjai Crowther, Bishop, Niger Territory, Oct. 19 1888 (from Page, p. iii)

Samuel Àjàyí Crowther (c. 1809 - December 31, 1891) jẹ́ onímọ̀ èdè Yorùbá àti Bíṣọ́ọ́bù akọ́kó fún ìjọ Anglican lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Òṣoògùn ní ìjọba Ìbílẹ̀ Ìsẹ́yìn ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Àwọn olówò ẹrú Fúlàní kóo mẹ́rú nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún méjìlá.[2] [3]


Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Samuel Ajayi Crowther". Encyclopedia.com. 2019-09-26. Retrieved 2019-09-27. 
  2. "Crowther, Samuel Adjai [or Ajayi] (c. 1807-1891)". History of Missiology. 2016-09-30. Retrieved 2019-09-27. 
  3. "Samuel Ajayi Crowther". Wikipedia. 2005-04-06. Retrieved 2019-09-27.