Ìṣèlú ilẹ̀ Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àyọkà yìí jẹ́ ìkan nínú àwọn àyọkà nípa
ìṣèlú àti ìjọba ilẹ̀
Nàìjíríà
 

Ìṣèlú ilẹ̀ Nàìjíríà je ti orile-ede NàìjíríàNigeria je Orile-ede Olominira Apapo bi orile-ede Amerika, pelu agbara apase lowo aare, be tun Naijiria tun ni apere sistemu Westminster ninu bi awon ile oke ati kekere asofin oniyewumeji. Sugbon, Aare ile Naijiria ni olori orile-ede ati olori ijoba, be si tun ni oun lo sistemu egbe oloselupupo. Iselu Naijiria unsele ninu alugba ijoba apapofederal, presidential, representative democratic republic, whereby Executive power is exercised by the government. Legislative power is vested in both the government and the two chambers of the legislature, the House of Representatives and the Senate. Together the two chambers make up the law-making body in Nigeria called the National Assembly. The highest judiciary arm of government in Nigeria is the Supreme Court of Nigeria. Nigeria also practices Baron de Montesquieu's theory of the separation of powers. The National Assembly serves as a watchdog to the excesses of the executive arm of government.

Sistemu abofinmu[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ofin ile Naijiria duro lori bi ilana ofin ba se wi ati ilominira adajo, be si tun o duro lori sistemu British common law—ni to ri ipa ti Britani amunisin ni. Sistemu abofinmu ri bakanna bi awon sistemu ofin wiwopo ti won lo ni Ilegeesi ati Welsi ati ni awo orile-ede Ajola miran. Alugba ilana-ibagbepo fun sistemu abofinmu je pipese ninu Ilana-ibagbepo Naijiria .



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]