Olórí ìjọba
Appearance
(Àtúnjúwe láti Head of government)
Olórí ìjọba ni osise agba tin o je apase ijoba[1], to solori ipade kabineeti. Ninu ilana ileasofin, olori ijoba ni a mo bi Alakoso Agba, tabi Aare Ijoba, Asiwaju, ati bee bee lo.[2] Ni ilana orile-ede olominira yiyan Aare tabi awon Oba alase, olori ijoba le je enikan naa bi olori orile-ede, ti an pe ni Aare tabi Oba.[3]
Awon Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "What is executive government?". lawgovpol.com. 2014-10-23. Retrieved 2018-05-20.
- ↑ "Meaning, Types and Functions of the Executive Organ of the Government". Political Science Notes. 2014-08-12. Retrieved 2018-05-20.
- ↑ "The Executive Branch". The White House. 1944-05-21. Retrieved 2018-05-20.