Olórí ìjọba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

This series is part of
the Politics series

Politics Portal

Olórí ìjọba ni osise agba apa apase ijoba, to solori ipade kabinet. Ninu sistemu onileasofin, olri ijoba ni a mo bi Alakoso Agba, Aare Ijoba, Asiwaju, at.be.be.lo. Ni sistemu orile-ede olominira ti aare tabi awon oba alase, olori ijoba le je enikanna bi olori orile-ede, ti an pe ni aare tabi oba.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]