Ìṣèlú ilẹ̀ Bòtswánà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ìṣèlú ilẹ̀ Bòtswánà je ti orile-ede Bòtswánà. Iselu ni Botswana unwaye labe eto orile-ede olominira oloselu asoju, nibi ti Ààrẹ ilẹ̀ Bòtswánà ti je olori orile-ede ati olori ijoba, ati labe sistemu egbe oloselu pupo. Agba apase wa lowo ijobat. Agbara Asofin wa lowo ijoba ati Iléaṣòfin ilẹ̀ Bòtswánà. Idiboyan aipe, ikewa iru re, waye ni ojo 16 Osu Kewa 2009.

Lati igba ilominira, oselu ni Botswana ti je gigaba latowo Egbe Oloselu Botswana. Adajo ni ilominira latodo apase ati asofin. Gege bi Isekedere Akariaye se so, Botswana ni orile-ede Afrika to ni iwa ibaje to din julo, be sini ipo re sunmo Portugal ato Korea Guusu.[1] Nevertheless the country is considered to have the most secretive public institutions.[2]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Transparency International 2008 Corruption Perception Index 2008. Retrieved 7-23-09.
  2. Glenda Daniels (2011-11-11) Botswana, Southern Africa's most secretive state. Mail & Guardian. mg.co.za