Ààrẹ ilẹ̀ Àngólà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àngólà
President of the Republic of Angola
Flag of the President of Angola.svg
2018-07-04 President João Lourenço-0555.jpg
Lọ́wọ́lọ́wọ́
João Lourenço

since 26 September 2017
Iye ìgbà5 years, renewable once
Ẹni àkọ́kọ́Agostinho Neto
Formation11 November 1975
DeputyVice President of Angola
Owó osù1,024,207.74 Kwanzas annually[1]
Emblem of Angola.svg
Àyọkà yìí jẹ́ ìkan nínú àwọn àyọkà nípa
ìṣèlú àti ìjọba ilẹ̀
Àngólà
 

Ààrẹ ilẹ̀ Àngólà (Pọrtugí: Presidente de Angola) ni olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba ní orílẹ̀-èdè Àngólà. Gẹ́gẹ́ bí òfin-ìbágbépọ̀ tí wọ́n gbàtọ́ ní ọdún 2010 ṣe sọ, ipò alákóso àgbà jẹ́ píparẹ́; agbára aláṣẹ bọ́ sí ọwọ́ áárẹ.

Ìgbà ẹ̀mejì fún ọdún márùún ní ààrẹ le fi wà ní ipò.

Ní Osù Kínní ọdún 2010 ni Iléìgbìmọ̀ Aṣòfin fọwọ́sí òfin-ìbágbépọ̀ tuntun, lábẹ́ òfin yìí, olórí ẹgbẹ́ ọ̀ṣèlú tó ní iye ìjókòó tó pọ̀ jùlọ ní iléaṣòfin ni yíò di ààrẹ, kò ní jẹ́ dídìbòyàn tààrà látọwọ́ àwọn aráàlú.[2]

João Lourenço ni Ààrẹ ilẹ̀ Àngólà lọ́wọ́lọ́wọ́, ó bọ́ sí orí ipò ní 26 September 2017.

Àtòjọ àwọn ààrẹ ilẹ̀ Àngólà (1975–d'òní)[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹ tún wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Angola topics

Àdàkọ:Heads of state and government of African states