José Eduardo dos Santos

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
José Eduardo dos Santos
José Eduardo dos Santos 2.jpg
Aare ile Angola
Lọ́wọ́
Ó bọ́ sí orí àga
10 September 1979
Aṣàkóso Àgbà Fernando José de França Dias Van-Dúnem
Marcolino Moco
Fernando José de França Dias Van-Dúnem
Fernando da Piedade Dias dos Santos
Paulo Kassoma
Asíwájú Agostinho Neto
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 28 Oṣù Kẹjọ 1942 (1942-08-28) (ọmọ ọdún 75)
Luanda, Angola
Ẹgbẹ́ olóṣèlú MPLA
Tọkọtaya pẹ̀lú Ana Paula dos Santos

José Eduardo dos Santos (ojoibi August 28, 1942[1]) ni Aare ile Angola lowolowo, o bo si ori aga ni odun 1979. Ohun na tun ni Aare egbe oloselu Popular Movement for the Liberation of Angola (MPLA).


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]