Dag Hammarskjöld
Appearance
Dag Hammarskjöld | |
---|---|
2nd Secretary-General of the United Nations | |
In office 10 April 1953 – 18 September 1961 | |
Asíwájú | Trygve Lie |
Arọ́pò | U Thant |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Jönköping, Sweden | 29 Oṣù Keje 1905
Aláìsí | 18 September 1961 Ndola, Federation of Rhodesia and Nyasaland | (ọmọ ọdún 56)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Swedish |
Dag Hjalmar Agne Carl Hammarskjöld ( Dag Hammarskjöld (ìrànwọ́·ìkéde)) (29 July 1905 – 18 September 1961) je diplomati, onimo oro-okowo ati oludako ara Swidin. O je Akowe Agba keji Aparapo awon Orile-ede lati April 1953 titi di ojo to se alaisi ninu ijamba baalu ni September 1961. Ohun nikan ni o gba Ebun Alafia Nobel leyin to se alaisi.[1] Bakanna Hammarskjöld nikan na tun ni Akowe Agba U.N. to se alaisi lenu ise.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Dag Hammarskjöld |