Henry Dunant

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Henry Dunant
Dunant as an elderly man
Ọjọ́ìbíJean Henri Dunant
(1828-05-08)8 Oṣù Kàrún 1828
Geneva, Switzerland
AláìsíOctober 30, 1910(1910-10-30) (ọmọ ọdún 82)
Heiden, Switzerland
Orílẹ̀-èdèSwiss
Iṣẹ́social activist, businessman, writer
Gbajúmọ̀ fúnFounder of the Red Cross
Parent(s)Jean-Jacques Dunant
Antoinette Dunant-Colladon
AwardsNobel Peace Prize (1901)

Jean Henri Dunant (May 8, 1828 – October 30, 1910), aka Henry Dunant, je ara Swiss onisowo ati alakitiyan awujo. Nigba irinajo owo to se ni 1859 o ri esi Ija Solferino ni Italy loni. O ko gbogbo iriri re sile ninu iwe to pe ni A Memory of Solferino eyi lo fa idasile Igbimo Kariaye Agbelebu Pupa (ICRC) ni 1863. Iwe Ipinnu Geneva odun 1864 duro lori adaro Dunant. Ni odun 1901 o gba Ebun Nobel Alafia akoko pelu Frédéric Passy.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]