Ẹ̀bùn Àláfíà Nobel

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ẹ̀bùn Nobel fún Àláfíà
The Nobel Prize in Peace
Bíbún fún Afikun pataki si Alafia
Látọwọ́ Norwegian Nobel Committee
Orílẹ̀-èdè Norway
Bíbún láàkọ́kọ́ 1901
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ http://nobelprize.org

Ẹ̀bùn Àláfíà Nobel (ede Scandinavia: Nobels fredspris) je ikan ninu awon Ebun Nobel marun ti Alfred Nobel fi lole ki oto ku.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]