Jump to content

Ẹ̀bùn Nobel fún Ìwòsàn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ẹ̀bùn Nobel fún Ìwòsàn
Nobel Prize in Physiology or Medicine
Bíbún fún Ipa pàtàkì nínú Ìwòsàn
Látọwọ́ Royal Swedish Academy of Sciences
Orílẹ̀-èdè Sweden
Bíbún láàkọ́kọ́ 1901
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ http://nobelprize.org

Ẹ̀bùn Nobel fún Ìwòsàn (Àdàkọ:Lang-sv) latowo Nobel Foundation, je ebun odoodun fun ipa pataki ninu ise iwosan. O je ikan larin awon ebun Nobel marun ti Alfred Nobel dasile ni 1895 sinu ogun re, awon yioku je fun ipa pataki ninu Fisiksi, Kemistri, Litireso ati Alafia.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]