Henrik Dam

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Henrik Dam

Henrik Dam (Oruko lekunrere Carl Peter Henrik Dam) (February 21, 1895 – April 17, 1976) je onimo kemistry alemin ati oro eda-ara ara Danish ti ohun ati Edward Doisy jo gba Ebun Nobel fun Iwosan ni 1943 fun ise ti won se fun sisawari fitamin K ati ipa re ninu oro eda-ara omo eniyan.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]