Robert G. Edwards
Ìrísí
Robert G. Edwards | |
---|---|
Robert G. Edwards (2010) | |
Ìbí | 27 Oṣù Kẹ̀sán 1925 Manchester |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | United Kingdom |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Cambridge |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Wales, Bangor University of Edinburgh |
Ó gbajúmọ̀ fún | reproductive medicine in-vitro fertilization |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Nobel Prize in Physiology or Medicine (2010) |
Robert Geoffrey Edwards, CBE FRS (ojoibi 27 September 1925, Manchester) je ara Britani onimo oro-alaaye ati eni akoko ninu iwosan atunrabi ati oro-alaaye, ati isejile ibimo lode ara (in-vitro fertilization; IVF) lagaga. Pelu onise abe Patrick Steptoe (1913 – 1988), Edwards se aseyori bibi omo tuntun pelu IVF, eyi fa ibimo omo inu igo akoko, Louise Brown, wa ni 25 July 1978.[1][2] O gba Ebun Nobel fun Iwosan 2010 "fun idagbasoke isejile ibimo lode ara".[3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "1978: First 'test tube baby' born". BBC. 1978-07-25. http://news.bbc.co.uk/onthisday/hi/dates/stories/july/25/newsid_2499000/2499411.stm. Retrieved 2009-06-13. "The birth of the world's first "test tube baby" has been announced in Manchester (England). Louise Brown was born shortly before midnight in Oldham and District General Hospital"
- ↑ Moreton, Cole (2007-01-14). "World's first test-tube baby Louise Brown has a child of her own". London: Independent. http://www.independent.co.uk/life-style/health-and-families/health-news/worlds-first-testtube-baby-louise-brown-has-a-child-of-her-own-432080.html. Retrieved 2010-05-22. "The 28-year-old, whose pioneering conception by in-vitro fertilisation made her famous around the world ... The fertility specialists Patrick Steptoe and Bob Edwards became the first to successfully carry out IVF by extracting an egg, impregnating it with sperm and planting the resulting embryo back into the mother."
- ↑ "The 2010 Nobel Prize in Physiology or Medicine - Press Release". Nobelprize.org. 2010-10-04. Retrieved 2010-10-04.