Mario Capecchi
Ìrísí
Mario Capecchi | |
---|---|
Ìbí | 6 Oṣù Kẹ̀wá 1937 Verona, Italy |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | United States |
Pápá | Genetics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | Harvard School of Medicine University of Utah |
Ibi ẹ̀kọ́ | George School Antioch College, Ohio Harvard University |
Ó gbajúmọ̀ fún | Knockout mouse |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Albert Lasker Award for Basic Medical Research (2001) Wolf Prize in Medicine (2002) Nobel Prize in Physiology or Medicine (2007) |
Religious stance | Quaker |
Mario Renato Capecchi (Verona, Italy, bíi Ọjọ́ Kẹfà Oṣù Kẹwa nìnù Ọd́n 1937) jẹ́ onímọ̀ ẹ̀kọ́ molecular genetics ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà tí wọ́n bí sí ilẹ̀ Italy tí ó gba Ẹ̀bùn Nobel nínú ìmọ̀ bí ara ṣe ń ṣiṣ́ẹ́ tàbí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fún ìlera ní ọdún 2007 fún ṣíṣe àwárí ọ̀nà tí a lè gbà dà eku, ní èyí tí a lè pa gene ẹ̀, tí àwọ́n olóyìnbó ń pè ní knockout mice.[1][2][3][4][5] Ó pín èbùn yí pẹ̀lú Martin Evans àti Oliver Smithies.[6]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Thomas, K. R.; Capecchi, M. R. (1987). "Site-directed mutagenesis by gene targeting in mouse embryo-derived stem cells". Cell 51 (3): 503–512. doi:10.1016/0092-8674(87)90646-5. PMID 2822260.
- ↑ Mansour, S. L.; Thomas, K. R.; Capecchi, M. R. (1988). "Disruption of the proto-oncogene int-2 in mouse embryo-derived stem cells: A general strategy for targeting mutations to non-selectable genes". Nature 336 (6197): 348–352. doi:10.1038/336348a0. PMID 3194019.
- ↑ Capecchi, M. R. (1980). "High efficiency transformation by direct microinjection of DNA into cultured mammalian cells". Cell 22 (2 Pt 2): 479–488. doi:10.1016/0092-8674(80)90358-x. PMID 6256082.
- ↑ Chisaka, O.; Capecchi, M. R. (1991). "Regionally restricted developmental defects resulting from targeted disruption of the mouse homeobox gene hox-1.5". Nature 350 (6318): 473–479. doi:10.1038/350473a0. PMID 1673020.
- ↑ Thomas, K. R.; Folger, K. R.; Capecchi, M. R. (1986). "High frequency targeting of genes to specific sites in the mammalian genome". Cell 44 (3): 419–428. doi:10.1016/0092-8674(86)90463-0. PMID 3002636.
- ↑ "The Nobel Prize in Physiology or Medicine 2007". Nobelprize.org. Retrieved 2007-10-08.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |