Jump to content

Henri La Fontaine

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Henri La Fontaine

Henri Marie La Fontaine (April 22,1854-May 14,1943) je eni to gba Ebun Nobel Alafia. O je omo bibi orile ede Brussels. O je ojogbon asofin nileloko,O je alagba ni ile igbimo as'ofin ni ilu Belgium fun odun merindinlogoji. O je onigbagbo to loruko, eni ti o si je alaseyori asa jakejado,ju gbogbo re lo,a si se akosile re fun agbanrere ati lapapo gbogbo agbaye. [1][2]

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "The Nobel Peace Prize 1913". NobelPrize.org. 1943-05-14. Retrieved 2020-03-03. 
  2. "Henri La Fontaine". Union of International Associations. 1943-05-14. Retrieved 2020-03-03.