Jane Addams

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jane Addams
Ọjọ́ìbí(1860-09-06)Oṣù Kẹ̀sán 6, 1860
Cedarville, Illinois
AláìsíMay 21, 1935(1935-05-21) (ọmọ ọdún 74)
Chicago, Illinois
Iṣẹ́American social reformer and Nobel Peace Prize recipient
Parent(s)John H. Addams and Sarah Weber

Jane Laura Addams A bí Addams ní 1860. Ó kú ní 1935. Ọmọ ilẹ̀ Àméríkà ni. Onímọ̀ nípa ẹ̀kọ́ tí wọ́n ń pè ní Sociology ni. Òun ni ó dá Hull House, Chicago sílẹ̀ ní 1889.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]