Javier Pérez de Cuéllar

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Javier Pérez de Cuéllar
Javier Pérez de Cuéllar.JPG
5th Secretary-General of the United Nations
Lórí àga
January 1, 1982 – January 1, 1992
Asíwájú Kurt Waldheim
Arọ́pò Boutros Boutros-Ghali
28th President of the Council of Ministers of Peru
Lórí àga
November 22, 2000 – July 28, 2001
President Valentín Paniagua
Asíwájú Federico Salas
Arọ́pò Roberto Dañino Zapata
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí Oṣù Kínní 19, 1920 (1920-01-19) (ọmọ ọdún 97)
Lima, Peru
Ọmọorílẹ̀-èdè  Peruvian
Tọkọtaya pẹ̀lú Marcela Temple Seminario
Ẹ̀sìn Roman Catholic

Javier Pérez de Cuéllar y de la Guerra (ojoibi 19 Osu Kinni, 1920, ni Lima) je diplomati ara Peru to je fifth Akowe Agba karun Aparapo awon Orile-ede lati ojo 1 Osu Kinni, 1982 de ojo 31 Osu Kejila, 1991.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]