Mobutu Sese Seko

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Mobutu Sésé Seko
Mobutu Sese Seko 1973.jpg
Aare ile Zaire
Lórí àga
24 November 1965 – 16 May 1997
Aṣàkóso Àgbà opolopo
Asíwájú Joseph Kasa-Vubu
Arọ́pò Laurent-Désiré Kabila
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 14 Oṣù Kẹ̀wá, 1930(1930-10-14)
Lisala, Belgian Congo
Aláìsí 7 Oṣù Kẹ̀sán, 1997 (ọmọ ọdún 66)
Rabat, Morocco
Ọmọorílẹ̀-èdè Congolese
Ẹgbẹ́ olóṣèlú Popular Movement of the Revolution
Tọkọtaya pẹ̀lú Marie-Antoinette Mobutu (alaisi)
Bobi Ladawa

Mobutu Sésé Seko Nkuku Ngbendu wa Za Banga (14 October 1930– 7 September 1997), to gbajumo gege bi Mobutu tabi Mobutu Sésé Seko (pípè /məˈbuːtuː ˈsɛseɪ ˈsɛkoʊ/), oruko abiso Joseph-Désiré Mobutu, lo di olori orile-ede Zaire (loni gege bi Olominira Toselu ile Kongo) leyin igba to fipagbajoba lowo Joseph Kasavubu.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]