Joseph Kabila
Jump to navigation
Jump to search
Joseph Kabila | |
---|---|
![]() Kabila in 2016 | |
4th President of the Democratic Republic of the Congo | |
In office 17 January 2001 – 24 January 2019 Acting: 17 January 2001 – 26 January 2001 | |
Alákóso Àgbà | Antoine Gizenga Adolphe Muzito Louis Alphonse Koyagialo (Acting) Augustin Matata Ponyo Samy Badibanga Bruno Tshibala |
Vice President | Azarias Ruberwa Arthur Z'ahidi Ngoma Abdoulaye Yerodia Ndombasi Jean-Pierre Bemba (2003–2006) |
Asíwájú | Laurent-Désiré Kabila |
Arọ́pò | Félix Tshisekedi |
Senator for life | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 15 March 2019 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Joseph Kabila Kabange 4 Oṣù Kẹfà 1971 Fizi, Congo-Léopoldville (now Democratic Republic of the Congo) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Party for Reconstruction and Democracy |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Olive Lembe di Sita (m. 2006) |
Alma mater | Makerere University People's Liberation Army National Defense University |
Military service | |
Allegiance | Àdàkọ:Country data DR Congo |
Branch/service | Armed Forces of the Democratic Republic of the Congo |
Rank | Major-general |
Joseph Kabila Kabange (lasan bi Joseph Kabila; ojoibi 4 Osu Kefa, 1971), ni Aare ti Orile-ede Olominira Toseluarailu ile Kongo (OOTK) lati 2001 ti de 2019 . O bo si ori aga ni Osu Kinni odun 2001, ojo mewa leyin iku oloro to pa baba re Laurent-Désiré Kabila to ti je aare OOTK. Ni 27 Osu Kokanla 2006, Joseph Kabila je mimudaju bi Aare leyin to ti bori ninu idiboyan gbogbogbo ti Osu Keje 2006.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
![]() |
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Joseph Kabila |