Aníbal Cavaco Silva
Ìrísí
Aníbal Cavaco Silva | |
---|---|
Aare ile Portugal | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 9 March 2006 | |
Alákóso Àgbà | José Sócrates Pedro Passos Coelho |
Asíwájú | Jorge Sampaio |
Alakoso Agba ile Portugal | |
In office 6 November 1985 – 28 October 1995 | |
Ààrẹ | António Ramalho Eanes Mário Soares |
Asíwájú | Mário Soares |
Arọ́pò | António Guterres |
Alakoso Eto Inawo | |
In office 10 January 1980 – 12 January 1981 | |
Alákóso Àgbà | Francisco de Sá Carneiro Diogo de Freitas do Amaral (Acting) |
Asíwájú | António Sousa Franco |
Arọ́pò | João Morais Leitão |
Omo Ileigbimo Asofin | |
In office 13 November 1980 – 30 May 1983 | |
In office 4 November 1985 – 26 October 1995 | |
Constituency | Lisbon |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 15 Oṣù Keje 1939 Boliqueime, Portugal |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Social Democratic Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Maria Alves da Silva |
Àwọn ọmọ | Patrícia Bruno |
Residence | Belém Palace |
Alma mater | Technical University of Lisbon University of York |
Profession | Economist Lecturer Financial adviser |
Signature | |
Website | Official website |
Aníbal António Cavaco Silva, GCC (Pípè ni Potogí: [ɐˈnibaɫ kɐˈvaku ˈsiɫvɐ]; born 15 July 1939), ni Aare orile-ede Portugal. O bori ninu idiboyan aare Portugal to waye ni 22 January 2006, o si tun je titun-diboyan ni 23 January 2011, fun igba keji odun marun. Cavaco Silva bura ni ojo 9 March 2006.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |