Konrad Adenauer

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Konrad Adenauer
Chancellor of Germany
In office
15 September 1949 – 16 October 1963
ÀàrẹTheodor Heuss (1949-1959)
Heinrich Lübke (1959-1969)
DeputyFranz Blücher (1949-1957)
Ludwig Erhard (1957-1963)
AsíwájúPosition established
Allied military occupation, 1945-1949
Count Lutz Schwerin von Krosigk (1945)
Arọ́pòLudwig Erhard
Foreign Minister of Germany
In office
15 March 1951 – 6 June 1955
ChancellorHimself
AsíwájúCount Lutz Schwerin von Krosigk (1945)
Arọ́pòHeinrich von Brentano
Mayor of Cologne
In office
1917–1933
AsíwájúLudwig Theodor Ferdinand Max Wallraf
Arọ́pòGünter Riesen
In office
1945–1945
AsíwájúRobert Brandes
Arọ́pòWilli Suth
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1876-01-05)5 Oṣù Kínní 1876
Cologne
Aláìsí19 April 1967(1967-04-19) (ọmọ ọdún 91)
Bad Honnef
Ẹgbẹ́ olóṣèlúCentre Party (1906-1945)
CDU (1945-1967)
(Àwọn) olólùfẹ́Emma Weyer
Auguste (Gussie) Zinsser
Alma materYunifásítì ìlú Freiburg
Yunifásítì ìlú Munich
Yunifásítì ìlú Bonn
OccupationLawyer, Politician

Wọ́n bí Konrad Adenauer ní 1876. Ó kú ní 1967. Òun ni Chancellor West German Federal Republic ní 1949 sí 1963. Òun ni ó dá Christain Democratic Party sílẹ̀ òun sì ni alága rẹ̀ láti 1945 títí di 1966. Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n ti ṣẹ́gun Jẹ́mánì tán, ó fún Jẹ́mánì ní òfin (Constitution) tí ó fi ni lọ́kàn balẹ́ Ó sì jẹ́ kí àwọn ìlú Òyìnbó yòókù fún Jẹ́mánì láyè nínú ẹgbẹ́ àfọwọ́sowọ́pọ̀ (Western Alliance) wọn. Ó sa gbogbo agbára láti jẹ́ kí ìparí ìjà wà láàrin ilẹ̀ Fransi àti Jẹ́mánì ṣùgbọ́n kò fi àyè (accommodation) gba Rọ́síà.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]