Takeo Miki

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Takeo Miki jẹ Alakoso Agba orile-ede Japan tele . Tíí ṣe alákoso Oòkà́n lé lógójí orílẹ èdè náà. Nì ọdún 1974 sí 1976. `Ọjọ ìbì rẹ ni ọjọ kẹtadínlógún, osu`̀ ketàlá, 1907 nì Awa, Tokushima. Ókú ní osù kewá, ọjọ kẹr̀inlá, 1988. Ó gba ìjoba lọ́wọ́ Kakuei Tanaka gẹgẹ bíi alákoso. Ìyàwó rẹ ni Matusko Miki. Ó kẹkọ jáde ní Meiji Unifásítì, Tokyo. Ó gba dókítà amòfin ní unifásíti`́ gúsù kalifónìa, Los ánjẹlísì.[1]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Pace, Eric (1988-11-14). "Takeo Miki, Japanese Premier in 70's, Dies at 81". The New York Times. Retrieved 2019-04-25.