Yukio Hatoyama

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Yukio Hatoyama
鳩山 由紀夫
Yukio Hatoyama.jpg
At the Metropolitan Museum of Art in New York.
Prime Minister of Japan
In office
16 September 2009 – 4 June 2010
Monarch Akihito
Deputy Naoto Kan
Asíwájú Taro Aso
Arọ́pò Naoto Kan
Member of the
Japanese House of Representatives
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
23 June 1986
Constituency 9th Hokkaidō District
Personal details
Ọjọ́ìbí 11 Oṣù Kejì 1947 (1947-02-11) (ọmọ ọdún 72)
Bunkyō, Japan
Ẹgbẹ́ olóṣèlu Democratic Party (1998–present)
Other political
affiliations
Liberal Democratic Party (Before 1993)
New Party Sakigake (1993–1996)
Democratic Party[1] (1996–1998)
Spouse(s) Miyuki Hatoyama (1975–present)
Children Kiichiro Hatoyama
Alma mater University of Tokyo
Stanford University
Profession Engineer
Professor
Website Official website

Yukio Hatoyama (鳩山由紀夫 Hatoyama Yukio?, ojoibi 11 February 1947) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Japan tó di Alákòóso Àgbà orílẹ̀-èdè Japan ní Ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 2009 (16 September 2009). Lọ́jọ́ kejì oṣù kẹfà ọdún 2010 (2 June 2010), Hatoyama kéde pé òun kọ̀wé fiṣẹ́lẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Alákóso Àgbà .[2]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]