Pedro Passos Coelho

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Pedro Passos Coelho
Pedro Passos Coelho 1.jpg
Alákóso àgbà orílẹ̀ èdè portugal
Lórí àga
Ọdún 2011 – Ọdún 2015
President Aníbal Cavaco Silva
Asíwájú José Sócrates
Constituency Vila Real
Lórí àga
4 November 1991 – 23 October 1999
Constituency Lisbon
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 24 Oṣù Keje 1964 (1964-07-24) (ọmọ ọdún 53)
Coimbra, Portugal
Ẹgbẹ́ olóṣèlú Social Democratic Party
Tọkọtaya pẹ̀lú Fátima Padinha (Divorced)
Laura Ferreira
Àwọn ọmọ Joana
Catarina
Júlia
Alma mater University of Lisbon
Lusíada University
Profession Economist
Ẹ̀sìn Roman Catholicism
Website Official website

Pedro Manuel Mamede Passos Coelho (Pípè ni Potogí: [ˈpeðɾu mɐnuˈɛɫ ˈpasuʃ kuˈeʎu]), (bíi ní Coimbra, ní Ọjọ́ kẹrìlélógún Ọsù keje Ọdún 1964) jẹ̣́ ọmọ orílẹ̀-èdè Portugal tó jẹ́ olùdarí ilé-iṣé, olóṣèlú, ààrẹ ẹgbẹ́ Social Democratic Party àti alakóso àgba orílẹ̀ èdè Portugal tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀.[1]

Àwọn ìtọ̣́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]