Jump to content

Aso Villa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Aso Villa
Àwòrán inú Aso Villa
Building
Architectural styleNeoclassical, Palladian
LocationYakubu Gowon Crescent, The Three Arms Zone, Asokoro, Abuja, FCT, Nigeria
OwnerFederal Government of Nigeria
Current tenantsMuhammadu Buhari, ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ìdílé rẹ̀
Coordinates9°03′44″N 7°31′07″E / 9.062270°N 7.518532°E / 9.062270; 7.518532Coordinates: 9°03′44″N 7°31′07″E / 9.062270°N 7.518532°E / 9.062270; 7.518532
Construction
StartedOṣù Kẹ̀wá 13, 1989; ọdún 34 sẹ́yìn (1989-10-13)
CompletedOṣù Kọkànlá 1, 1991; ọdún 32 sẹ́yìn (1991-11-01)

Aso villa jé ilè ibùgbé fún Ááre orílè-èdè Nàìjíríà láti odún 1991(Nígbà tí Olori ologun Ibrahim Badamasi Babangida so ìlú Abuja di Olú ìlú Nàìjíríà). Aso villa wa ní Ìlú Abuja, àwon olùgbé re si ni Àárè Muhammadu Buhari àti idile rè[1]

Kíkó Aso Villa bere ni ojo Ketala osu kewa odún 1989, ásì pari kíkó rè ní ojo kini, osu kokanla tí odún 1991[1]

Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "The Villa – The Statehouse, Abuja". The Statehouse, Abuja. 2018-01-13. Retrieved 2022-02-24. 
  2. "Aso Villa". Wikipedia. 2005-08-18. Retrieved 2022-02-24. 
  1. 1.0 1.1 "The Villa – The Statehouse, Abuja". The Statehouse, Abuja. 2018-01-13. Retrieved 2023-04-07.