Aginjù
Ìrísí
Aginjù ni is a barren area of apá ilẹ̀ gbígbẹ tí kò sí ìsú-òjò rárá, nítórí bẹ́ẹ̀, ìgbésíayé le fún àwọn ọ̀gbìn àti ẹranko níbẹ̀. Àìsí ewéko jẹ́ kí orí ilẹ̀ kó mọ́ nìí àbò rárá, ilẹ̀ le là tàbí kó fọ́. Bíi ìdá kan nínú mẹ́ta ilẹ̀ ilé-ayé ni wọ́n jẹ́ ọ̀gbẹlẹ̀ tàbí ọ̀gbẹlẹ̀ díẹ̀.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |