Jump to content

Agnes Osazuwa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use Nigerian English

Agnes Osazuwa
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí26 Oṣù Kẹfà 1989 (1989-06-26) (ọmọ ọdún 35)
Benin, Ìpínlẹ̀ Edo

Agnes Osazuwa tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1989 (26 June 1989) ní ìlú Benin, Ìpínlẹ̀ Edo jẹ́ eléré-ìjẹ lórí pápá ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó máa ń díje fún Nàìjíríà.[1]

Agnes ṣojú Nigeria ní ìdíje Òlímpíkì ti ọdún 2008 ní Beijing, lórílẹ̀-èdè China, ó díje nínú eré gbagigbagi onìwọ̀n mita 4x100 pẹ̀lú Gloria Kemasuode, Olúdàmọ́lá Ọ̀sáyọ̀mi àti Ene Franca Idoko. Ó tún kópa nínú ìdíje gbagigbagi oníwọ̀n mítà 4x100. Wọ́n gba àmìn-ẹ̀yẹ ipò kẹta nínú àṣekágbá ìdíje náà. Orílẹ̀-èdè Russia àti Belgium ni wọ́n gba ipò kìíní àti kejì.[1] lọ́dún 2016, wọn gba ipò kìíní ìdíje náà lọ́wọ́ orílẹ̀ èdè Russia, nítorí pé ọ̀kan nínú àwọn olùdíje náà, Yuliya Chermoshanskaya ní àṣírí rẹ̀ tú pé ó lógún olóró, èyí ní wón fi wá fi Nàìjíríà sí ipò kejì dípò ipò kẹta tí wọ́n kọ́kọ́ wà tẹ́lẹ̀.[2]

Àwọn àṣeyọrí ìdíje rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Representing Nàìjíríà Nàìjíríà
2008 World Junior Championships Bydgoszcz, Poland 9th (sf) 100m 11.68 (wind: -0.7 m/s)
12th (h) 4 × 100 m relay 45.30
Olympic Games Beijing, PR China 2nd 4 × 100 m relay 43.04 s

Àwọn ìtọ́kasí ìta

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Authority control


Àdàkọ:Nigeria-Olympic-medalist-stub Àdàkọ:Nigeria-athletics-bio-stub

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]