Aguma Igochukwu
Ìrísí
Aguma Igochukwu je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà láti ìjọba ìbílè Port Harcourt ni Ipinle Rivers ni Naijiria . Ó sìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin, ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin orílẹ̀-èdè, tí ó ń ṣojú ẹkùn ìpínlẹ̀ Port Harcourt láti ọdún 2007 sí 2011. Bakan naa lo tun je alága ẹgbẹ òṣèlú All Progressives Congress (APC). [1] [2]