Aguma Nnamdirim
Ìrísí
Aguma Nnamdirim | |
---|---|
Member of the House of Representatives | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 2003 | |
Constituency | Port Harcourt Federal Constituency 1 |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Peoples Democratic Party |
Aguma Nnamdirim je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Naijiria ati aṣofin lati Ìpínlẹ̀ Rivers, Nigeria . O ti ṣiṣẹ ni ọpọlọpọ awọn ipo iṣelu ni Ipinlẹ Rivers, pẹlu Komisona ti èrè ìdárayá lákòókò Peter Odili ni ọdun 1999. O jawe olubori ninu idibo ile ìgbìmọ̀ asofin àgbà karun-un ni Ìpínlẹ̀ Rivers ni odun 2003 labẹ ẹgbẹ́ oselu Peoples Democratic Party (PDP), to n soju Port Harcourt 1 ni ile igbimo asofin. O tun ti ṣiṣẹ gẹgẹbi Senato Ìgbìmò Ile lori Awọn orisun Gas ni Ìpínlẹ̀ Rivers. [1]