Jump to content

Ahmed Isah

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ahmed Isah
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ìgbà iṣẹ́2009 — present
Gbajúmọ̀ fúnAnchor of Brekete Family

Ahmed Isah jẹ́ alágbára àti olóòtú eré orí rédíò ní Nàìjíríà, tí amọ̀ pátákì jùlọ gẹ́gẹ́ bí olótù eré rédíò tí a mọ̀ sí Brekete Family, èyí tó ń lọ ní Human Rights Radio.

Ìtàn Ìgbésí ayé

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Isah jẹ́ ọmọ ìbílẹ̀ IdanreÌpínlẹ̀ Òndó. Ní ọdún 2009, ó dá eré rédíò tó jẹ́ Brekete Family sílẹ, èyí tó kọ́kọ́ jáde sí Kiss FM.[1][2] Ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kàrún ọdún 2021, Peter Nkanga, oníwáádìí to jẹ́ gbajúmọ̀ ní BBC, ṣe fíìmù nípa ìfìyajẹ̀ tó ṣẹlẹ̀ ní ọwọ́ Isah sí obìnrin kan tó wá nípa ẹ̀ṣẹ̀ tó ní í ṣe pẹ̀lú ọmọ tí ó lu jà.[3][4] Lẹ́yìn ẹ̀, Isah bẹbẹ fún àfọ̀rìjìn, ó sì sọ pé òún ní iṣoro ìbínú.[5][6][7] Lẹ́yìn ìṣẹlẹ náà, léyìn ọ̀jọ diẹ̀, àwọn ọlọ́pàá ní Abuja gbé,[8] wọ́n sì gbá àsẹ ìròyìn tí National Broadcasting Commission lọwọ́ rẹ.[9][10]

Mohammed Eibo Namiji, tó nkọ̀wé fún Blueprint sọ pé ìṣẹlẹ náà jé ẹ̀sùn ìkàkànsí lòdì sí Isah.[11] Wón síi padà tú sílẹ̀ kúrò nínú àtìmólè.[12]

Ní January 2022, Fabian Benjamin, òṣìsẹ́ JAMB, fi ẹsùn ìlò dì sí ẹ̀tọ́ orúkọ kán Isah, wọ́n sì béèrè owó ẹ̀tọ to tó bílíọ̀nù mẹ́fà náírà lọwọ́ rẹ.[13][14]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Isah, Ahmad (5 May 2018). "God made me something out of nothing". https://www.blueprint.ng/god-made-something-nothing-ahmad-isah/. 
  2. Egbejule, Eromo (18 March 2014). "'Ordinary' Ahmed Isah: Meet the fiery man who is shaking Abuja up with 'Brekete' (YNaija Long Read)". YNaija. Archived from the original on 12 March 2022. Retrieved 12 March 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. Nkanga, Peter (17 May 2021). "Nigeria's Ordinary President" (video). BBC News Africa. Retrieved 12 March 2022 – via YouTube. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  4. "Africa Eye: Ahmed Isah, "Nigeria Ordinary President"". BBC News Pidgin. 17 May 2021. Archived from the original on 12 March 2022. Retrieved 12 March 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Sahara Reporters (19 May 2021). "Brekete Family Show's Ahmed Isah Announces Plan To Quit Programme Over Assault Of Woman". Sahara Reporters. Archived from the original on 12 March 2022. Retrieved 12 March 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. Lere, Mohammed; Fadare, Titilope (20 May 2021). "AUDIO: Brekete show anchor, Ahmed Isah, apologises for slapping interviewee". Premium Times. Archived from the original on 12 March 2022. Retrieved 12 March 2022. The interviewee was accused for burning her little niece's hair whom she claimed is a witch.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. Akpan, Samuel (31 May 2021). "Ahmad Isah, Brekete radio host, says he's short-tempered, prays for 'good temperament'". TheCable. Archived from the original on 12 March 2022. Retrieved 12 March 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. Sahara Reporters (25 May 2021). "BBC Documentary: Police Arrest, Detain Brekete Radio CEO, Ahmed Isah Over Assault". Sahara Reporters. Archived from the original on 12 March 2022. Retrieved 12 March 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. Oluwafemi, Ayodele (17 May 2021). "Ahmad Isah, Brekete Family host, comes under scrutiny in BBC documentary". TheCable. Archived from the original on 12 March 2022. Retrieved 12 March 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  10. "Ahmed Isah Brekete family programme dey go off air as NBC suspend Human Rights Radio Station license". BBC News Pidgin. 27 May 2021. Archived from the original on 12 March 2022. Retrieved 12 March 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  11. Eibo Namiji, Mohammed (1 June 202). "The travails of Ahmad Isah". Blueprint. Archived from the original on 1 June 2021. Retrieved 12 March 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help); Check date values in: |date= (help)
  12. Opejobi, Seun (25 May 2021). "Ordinary President has left FCT Police Command – Brekete". Daily Post. Archived from the original on 12 March 2022. Retrieved 12 March 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  13. Suleiman, Qosim (31 January 2022). "Alleged Defamation: JAMB official sues Brekete show anchor, Ahmed Isah". Premium Times. Archived from the original on 12 March 2022. Retrieved 12 March 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  14. Erunke, Joseph (31 January 2022). "Alleged defamation: JAMB PRO drags Ahmed Isah, Human Rights Radio to court". Vanguard. Archived from the original on 12 March 2022. Retrieved 12 March 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)