Jump to content

Aisha Abimbola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Aisha Abimbola (tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún, oṣù Kejìlá, ọdún 1970, tí ó sì kú ní ọjọ́ karùn-úndínlógún, oṣù kàrún, ọdún 2018)[1] jẹ́ òṣèrébìnrin ti ìlẹ̀ Nàìjíríà ó sì tún jẹ́ òṣèré Yorùbá tó gbayì.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Aisha Abimbola Biography". LATEST NIGERIAN NEWS BREAKING HEADLINES NEWSPAPERS (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-05-18. Retrieved 2020-11-10. 
  2. "Nigerian Actress Aisha Abimbola Laid to Rest in Canada". allAfrica.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-05-17. Retrieved 2020-11-10.