Aisha Falode
Ìrísí
Aisha Falode | |
---|---|
Aisha Falode jẹ́ oniroyin fún èrè orí pàápàá ni Nàìjíríà. Òun ní olórí fún ẹgbẹ́ agbaboolu obìnrin fún orílè-èdè Nàìjíríà.[1][2] Ó wá láàrin àwọn òṣìṣẹ́ tí ó kọ́kọ́ bẹẹ rẹ̀ ní ilé iṣẹ́ telefisionu tí African Independent Television. Ó ti si ṣé pelu Nigerian Telecommunication Limited àti Graduate Telephone Operators Scheme.[3][4][5] Ó jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórí rádíiò, ó sì má sọ̀rọ̀ nípa eré orí pàápàá.[6] Ní oṣù kìíní ọdún 2017, wọn fi jẹ olórí ẹgbẹ́ agbaboolu obìnrin fún orílè-èdè Nàìjíríà.[7]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "NWFL board mourns death of Nasarawa Amazons chairman". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-04. Retrieved 2019-04-07.
- ↑ Newspapers, BluePrint (2019-03-31). "Lagos agog for AITEO/NFF event, FIFA Scribe set to pick award". Blueprint (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-07.
- ↑ BellaNaija.com (2014-05-04). "Aisha Falode seeks Justice for her 19 Year Son Toba who died in Dubai". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-07.
- ↑ "I love Jean trousers and T-shirts - Falode". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2012-03-15. Retrieved 2019-04-07.
- ↑ "Asia is fast becoming dominant in football - Aisha Falode". The Nation Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-03-17. Retrieved 2019-04-07.
- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 2014-02-15. Retrieved 2014-08-13. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Aisha Falode inaugurated board chair of Nigeria Women Football League". Premium Times. Retrieved 2017-10-05.
Àwọn ẹ̀ka:
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)
- Pages with citations using unsupported parameters
- Articles which use infobox templates with no data rows
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Nigerian television journalists
- Year of birth missing (living people)
- Yoruba journalists
- Nigerian women journalists
- Women television journalists
- 21st-century Nigerian women