Jump to content

Aisha Kyomuhangi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Aisha Kyomuhangi
Orílẹ̀-èdèUgandan
Iṣẹ́
  • CEO of Faisha Pictures International (2018–present)
  • Singer
  • actress
  • film producer
Ìgbà iṣẹ́2006–present

Aisha Kyomuhangi tí orúkọ ìnagi rẹ̀ jẹ́ Lady Aisha jẹ́ òṣèré, olórin àti olùgbé jáde eré lórílẹ̀-èdè Uganda. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Bakayimbira Drama tors.[1][2]

Aisha tí ṣe eré fún ọdún tó lé ní ogún. Ó kopa nínú àwọn eré bíi The Last King of Scotland, Byansi ,The Honorables àti Mistakes Galz Do. Ní ọdún 2019, ó gbé eré Kemi jáde, èyí sì ni eré tí ó má kọ́kọ́ gbé jáde.[3][4][5] Wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré tó dára jù lọ[6] fún ipa tí ó kó nínú eré Honourablez[7][8] Ní ọdún 2002, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin tuntun tó dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ Pearl of Africa Music Awards.[9][10]

Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìgbésí ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Aisha jẹ́ ìyàwó fún Charles Ssenkugbe, ó sì ti bí ọmọ kan.[15]

Àwọn Ìtọ́kàsi

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. https://www.newvision.co.ug/news/1143485/unveiling-lady-aisha
  2. Kaaya, Sadab Kitatta. "Kazakhstan: one country, two continents". The Observer - Uganda (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-10-19. Retrieved 2020-09-28. 
  3. https://www.ghmoviefreak.com/movie-review-kemi-the-final-tragedy/
  4. "Meet the Women Behind 'KEMI'- The Final Tragedy". Glim (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-03-03. Archived from the original on 2020-09-11. Retrieved 2020-09-28. 
  5. Technologies, Buzen. "KEMI MOVIE PREMIERING 8TH MARCH 2020.". www.cinemaug.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-10-17. Retrieved 2020-09-28. 
  6. "Ẹda pamosi" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2021-11-24. Retrieved 2020-11-25. 
  7. "FULL LIST: UCC releases list of movies nominated for Uganda Film Festival awards 2019". PML Daily (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-11-08. Retrieved 2020-09-28. 
  8. "Ẹda pamosi" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2021-11-24. Retrieved 2020-11-25. 
  9. https://www.newvision.co.ug/news/1141246/pam-awards-nods-boost-artistes
  10. https://web.archive.org/web/20100522040255/http://www.musicuganda.com/pamnominees2006.html
  11. Mulumba, Abu-Baker. "Bakayimbira, Afri Talent in Enyana Ekutudde". The Observer - Uganda (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-12-12. Retrieved 2020-09-28. 
  12. Mulumba, Abu-Baker. "Ndiwulira back on time". The Observer - Uganda (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-12-12. Retrieved 2020-09-28. 
  13. Batte, Edgar R. "The Honourablez, baring out the excesses of MPs – Sqoop – Get Uganda entertainment news, celebrity gossip, videos and photos" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-09-28. 
  14. Ugandacommunicationscommission (2019-11-08). "NOMINATIONS LIST -UFF2019". Uganda Communications Commission Blog (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-10-24. Retrieved 2020-09-28. 
  15. www.newvision.co.ug https://www.newvision.co.ug/news/1217122/it-eur-okay-wife. Retrieved 2020-09-28.  Missing or empty |title= (help)