Aisha Masaka

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Aisha Masaka
Personal information
Ọjọ́ ìbíọjọ́ kẹ̀wá Oṣù kọkànlá ọdún 2003
Ibi ọjọ́ibíSingida, Tanzania[1]
Ìga1.75 m[1]
Playing positionForward, winger[1]
Club information
Current clubBK Häcken
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
-2021Young Africans
2022–BK Häcken0(0)
National team
2021–Tanzania4(2)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 2 October 2021.[2]

Aisha Masaka tí a bí ní ọjọ́ kẹ̀wá Oṣù kọkànlá ọdún 2003 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀ède Tanzania tí ó ṣeré ipò iwájú lórí pápá fún BK Häcken ní Damallsvenskan àti ẹgbẹ́ <a href="./Boolu-afesegba" rel="mw:WikiLink">agbábọ́ọ̀lù</a> obìnrin ti ilẹ̀ Tanzania .

Isẹ́ ẹgbẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Masaka ti ṣeré fún àwọn ọ̀dọ́ Afirika ní Tanzania.

Isẹ́ òkè-òkun[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Masaka ti sojú fún Tanzania ní ìpele àgbà ní àkókò ìdíje COSAFA Women's championship ní ọdún 2021 .

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named LTAA
  2. Àdàkọ:GSA player